Yorùbá Bibeli

Neh 12:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati awọn arakunrin rẹ̀, Ṣemaiah, ati Asaraeli, Milalai, Gilalai, Maai, Netaneeli, ati Juda, Hanani, pẹlu ohun èlo orin Dafidi, enia Ọlọrun, ati Esra akọwe niwaju wọn.

Neh 12

Neh 12:34-38