Yorùbá Bibeli

Neh 11:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

AWỌN olori awọn enia si ngbe Jerusalemu: awọn enia iyokù si dìbo lati mu ẹnikan ninu ẹnimẹwa lati ma gbe Jerusalemu, ilu mimọ́, ati mẹsan iyokù lati ma gbe ilu miran.

Neh 11

Neh 11:1-7