Yorùbá Bibeli

Mat 9:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu si rìn si gbogbo ilu-nla ati iletò, o nkọni ninu sinagogu wọn, o si nwãsu ihinrere ijọba, o si nṣe iwòsan arun ati gbogbo àisan li ara awọn enia.

Mat 9

Mat 9:30-38