Yorùbá Bibeli

Mat 5:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn jẹ ki ọ̀rọ nyin jẹ, Bẹ̃ni, bẹ̃ni; Bẹ̃kọ, bẹ̃kọ; nitoripe ohunkohun ti o ba jù wọnyi lọ, nipa ibi li o ti wá.

Mat 5

Mat 5:30-45