Yorùbá Bibeli

Mat 5:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ jẹ ki imọlẹ nyin ki o mọlẹ tobẹ̃ niwaju enia, ki nwọn ki o le mã ri iṣẹ rere nyin, ki nwọn ki o le ma yìn Baba nyin ti mbẹ li ọrun logo.

Mat 5

Mat 5:14-19