Yorùbá Bibeli

Mat 28:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Angẹli na si dahùn, o si wi fun awọn obinrin na pe, Ẹ má bẹ̀ru: nitori emi mọ̀ pe ẹnyin nwá Jesu, ti a ti kàn mọ agbelebu.

Mat 28

Mat 28:3-12