Yorùbá Bibeli

Mat 27:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si hun ade ẹgún, nwọn si fi dé e li ori, nwọn si fi ọpá iyè le e li ọwọ́ ọtún: nwọn si kunlẹ niwaju rẹ̀, nwọn si fi i ṣẹsin, wipe, Kabiyesi, ọba awọn Ju.

Mat 27

Mat 27:20-39