Yorùbá Bibeli

Mat 24:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn niti ọjọ ati wakati na, kò si ẹnikan ti o mọ̀ ọ, awọn angẹli ọrun kò tilẹ mọ̀ ọ, bikoṣe Baba mi nikanṣoṣo.

Mat 24

Mat 24:31-44