Yorùbá Bibeli

Mat 23:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Egbé ni fun nyin, ẹnyin akọwe ati Farisi, agabagebe; nitoriti ẹnyin kọ́ ibojì awọn wolĩ, ẹnyin si ṣe isà okú awọn olododo li ọṣọ,

Mat 23

Mat 23:22-33