Yorùbá Bibeli

Mat 20:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o di oju alẹ oluwa ọgba ajara wi fun iriju rẹ̀ pe, Pè awọn alagbaṣe nì, ki o si fi owo agbaṣe wọn fun wọn, bẹ̀rẹ lati ẹni ikẹhin lọ si ti iṣaju.

Mat 20

Mat 20:1-16