Yorùbá Bibeli

Mat 20:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun wọn pe; Ẹ lọ si ọgba ajara pẹlu, ohunkohun ti o ba tọ́ emi o fifun nyin. Nwọn si mu ọ̀na wọn pọ̀n lọ sibẹ̀.

Mat 20

Mat 20:1-5