Yorùbá Bibeli

Mat 20:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Si kiyesi i, awọn ọkunrin afọju meji joko leti ọ̀na, nigbati nwọn gbọ́ pe Jesu nrekọja, nwọn kigbe soke, wipe, Oluwa, iwọ Ọmọ Dafidi, ṣãnu fun wa.

Mat 20

Mat 20:25-34