Yorùbá Bibeli

Mat 18:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin ti rò o si? bi ọkunrin kan ba ni ọgọrun agutan, bi ọkan nù ninu wọn, kì yio fi mọkandilọgọrun iyokù silẹ̀, kì yio lọ sori òke lọ iwá eyi ti o nù bi?

Mat 18

Mat 18:10-20