Yorùbá Bibeli

Mat 15:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tobẹ̃, ti ẹnu yà ijọ enia na, nigbati nwọn ri ti odi nfọhùn, ti arọ ndi ọ̀tọtọ, ti amukun nrìn, ti afọju si nriran: nwọn si yìn Ọlọrun Israeli logo.

Mat 15

Mat 15:27-38