Yorùbá Bibeli

Mat 15:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Jesu dahùn o si wi fun u pe, Obinrin yi, igbagbọ́ nla ni tirẹ: ki o ri fun ọ gẹgẹ bi iwọ ti nfẹ. A si mu ọmọbinrin rẹ̀ larada ni wakati kanna.

Mat 15

Mat 15:26-34