Yorùbá Bibeli

Mat 14:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn enia ibẹ̀ si mọ̀ pe on ni, nwọn ranṣẹ lọ si gbogbo ilu na yiká, nwọn si gbé gbogbo awọn ọlọkunrùn tọ̀ ọ wá.

Mat 14

Mat 14:30-36