Yorùbá Bibeli

Mak 9:45 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ẹsẹ rẹ ba si mu ọ kọsè, ke e kuro: o sàn fun ọ ki o ṣe akesẹ lọ si ibi ìye, jù ki o li ẹsẹ mejeji ki a gbé ọ sọ si ọrun apadi, sinu iná ajõku,

Mak 9

Mak 9:37-47