Yorùbá Bibeli

Mak 9:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori o kọ́ awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀, o si wi fun wọn pe, A o fi Ọmọ-enia le awọn enia lọwọ nwọn o si pa a; lẹhin igbati a ba si pa a tan, yio jinde ni ijọ kẹta.

Mak 9

Mak 9:29-33