Yorùbá Bibeli

Mak 9:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nibikibi ti o ba gbé si mu u, a si ma nà a tantan: on a si ma yọ ifofó li ẹnu, a si ma pahin keke, a si ma daku; mo si sọ fun awọn ọmọ-ẹhin rẹ, ki nwọn lé e jade; nwọn ko si le ṣe e.

Mak 9

Mak 9:12-20