Yorùbá Bibeli

Mak 2:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi o si ti nkọja lọ, o ri Lefi ọmọ Alfeu, o joko ni bode, o si wi fun u pe, Mã tọ̀ mi lẹhin. O si dide, o tọ̀ ọ lẹhin.

Mak 2

Mak 2:5-18