Yorùbá Bibeli

Mak 2:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si dide lojukanna, o si gbé akete na, o si jade lọ li oju gbogbo wọn; tobẹ̃ ti ẹnu fi yà gbogbo wọn, nwọn si yìn Ọlọrun logo, wipe, Awa ko ri irú eyi rí.

Mak 2

Mak 2:6-21