Yorùbá Bibeli

Mak 15:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnikan si wà ti a npè ni Barabba, ẹniti a sọ sinu tubu pẹlu awọn ti o ṣọ̀tẹ pẹlu rẹ̀, awọn ẹniti o si pania pẹlu ninu ìṣọtẹ na.

Mak 15

Mak 15:4-15