Yorùbá Bibeli

Mak 15:46 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si rà aṣọ ọgbọ wá, o si sọ̀ ọ kalẹ, o si fi aṣọ ọgbọ na dì i, o si tẹ́ ẹ sinu ibojì ti a gbẹ́ ninu apata, o si yi okuta kan di ẹnu-ọ̀na ibojì na.

Mak 15

Mak 15:36-47