Yorùbá Bibeli

Mak 15:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si fi i ṣẹ̀sin tan, nwọn si bọ́ aṣọ elesè àluko na kuro lara rẹ̀, nwọn si fi aṣọ rẹ̀ wọ̀ ọ, nwọn si mu u jade lọ lati kàn a mọ agbelebu.

Mak 15

Mak 15:14-28