Yorùbá Bibeli

Mak 14:48-50 Yorùbá Bibeli (YCE)

48. Jesu si dahùn o si wi fun wọn pe, Emi li ẹnyin jade tọ̀ wá bi olè, ti ẹnyin ti idà ati ọgọ lati mu?

49. Li ojojumọ li emi wà pẹlu nyin ni tẹmpili, ti emi nkọ́ nyin, ẹnyin kò si mu mi: ṣugbọn iwe-mimọ kò le ṣe alaiṣẹ.

50. Gbogbo wọn si fi i silẹ, nwọn si sá lọ.