Yorùbá Bibeli

Mak 14:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si wà ni Betani ni ile Simoni adẹtẹ̀, bi o ti joko tì onjẹ, obinrin kan ti o ni oruba alabasta ororo ikunra nardi iyebiye, o wá, o si fọ́ orúba na, o si ndà a si i lori.

Mak 14

Mak 14:1-11