Yorùbá Bibeli

Mak 14:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitõtọ Ọmọ-enia nlọ bi a ti kọwe nipa tirẹ̀: ṣugbọn egbé ni fun ọkunrin na, lọdọ ẹniti a gbé ti fi Ọmọ-enia hàn! iba san fun ọkunrin na, bi o ṣepe a kò bí i.

Mak 14

Mak 14:12-31