Yorùbá Bibeli

Mak 14:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si rán awọn meji ninu awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀, o si wi fun wọn pe, Ẹ lọ si ilu, ọkunrin kan ti nrù ìṣa omi yio pade nyin: ẹ mã tọ̀ ọ lẹhin.

Mak 14

Mak 14:9-21