Yorùbá Bibeli

Mak 14:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

LẸHIN ọjọ meji ni ajọ irekọja, ati ti aiwukara: ati awọn olori alufa ati awọn akọwe nwá ọ̀na bi nwọn iba ti fi ẹ̀tan mu u, ki nwọn ki o pa a.

Mak 14

Mak 14:1-10