Yorùbá Bibeli

Mak 13:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ẹ mã kiyesara nyin: nitori nwọn ó si fi nyin le awọn igbimọ lọwọ; a o si lù nyin ninu sinagogu: a o si mu nyin duro niwaju awọn balẹ ati awọn ọba nitori orukọ mi, fun ẹrí si wọn.

Mak 13

Mak 13:1-15