Yorùbá Bibeli

Mak 11:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina mo wi fun nyin, Ohunkohun ti ẹnyin ba tọrọ nigbati ẹ ba ngbadura, ẹ gbagbọ́ pe ẹ ti ri wọn gbà na, yio si ri bẹ̃ fun nyin.

Mak 11

Mak 11:22-29