Yorùbá Bibeli

Mak 11:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ri igi ọpọtọ kan li òkere ti o li ewé, o wá, bi bọya on le ri ohun kan lori rẹ̀: nigbati o si wá si idi rẹ̀, ko ri ohun kan, bikoṣe ewé; nitori akokò eso ọpọtọ kò ti ito.

Mak 11

Mak 11:12-23