Yorùbá Bibeli

Mak 10:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Jesu pè wọn sọdọ rẹ̀, o si wi fun wọn pe, Ẹnyin mọ̀ pe, awọn ti a nkà si olori awọn Keferi, a ma lò ipá lori wọn: ati awọn ẹni-nla wọn a ma fi ọlá tẹri wọn ba.

Mak 10

Mak 10:35-50