Yorùbá Bibeli

Mak 10:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si wi fun u pe, Awa le ṣe e. Jesu si wi fun wọn pe, Lõtọ li ẹnyin ó mu ago ti emi mu; ati baptismu ti a o fi baptisi mi li a o fi baptisi nyin:

Mak 10

Mak 10:33-49