Yorùbá Bibeli

Mak 10:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun wọn pe, Ẹnikẹni ti o ba fi aya rẹ̀ silẹ, ti o ba si gbé omiran ni iyawo, o ṣe panṣaga si i.

Mak 10

Mak 10:3-13