Yorùbá Bibeli

Mak 1:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wà ni ogoji ọjọ ni ijù, a ti ọwọ́ Satani dán an wò, o si wà pẹlu awọn ẹranko igbẹ́; awọn angẹli si nṣe iranṣẹ fun u.

Mak 1

Mak 1:3-20