Yorùbá Bibeli

Luk 9:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn aposteli si pada de, nwọn ròhin ohun gbogbo fun u ti nwọn ti ṣe. O si mu wọn, o si lọ si apakan nibi ijù si ilu ti a npè ni Betsaida.

Luk 9

Luk 9:1-14