Yorùbá Bibeli

Luk 8:49 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi o si ti nsọ̀rọ li ẹnu, ẹnikan ti ile olori sinagogu wá, o wi fun u pe, Ọmọbinrin rẹ kú; má yọ olukọni lẹnu mọ.

Luk 8

Luk 8:44-56