Yorùbá Bibeli

Luk 8:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ ki ẹnyin ki o mã kiyesara bi ẹnyin ti ngbọ́: nitori ẹnikẹni ti o ba ni, on li a o fifun; ati ẹnikẹni ti kò ba si ni, lọwọ rẹ̀ li a o si gbà eyi ti o ṣebi on ni.

Luk 8

Luk 8:13-28