Yorùbá Bibeli

Luk 7:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Jesu gbọ́ nkan wọnni, ẹnu yà a si i, o si yipada si ijọ enia ti ntọ̀ ọ lẹhin, o wipe, Mo wi fun nyin, emi kò ri irú igbagbọ́ nla bi eyi ninu awọn enia Israeli.

Luk 7

Luk 7:5-11