Yorùbá Bibeli

Luk 7:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu si mba wọn lọ. Nigbati kò si jìn si eti ile mọ́, balogun ọrún na rán awọn ọrẹ́ si i, wipe, Oluwa, má yọ ara rẹ lẹnu: nitoriti emi kò to ti iwọ iba fi wọ̀ abẹ orule mi:

Luk 7

Luk 7:3-8