Yorùbá Bibeli

Luk 7:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn ọkunrin na si de ọdọ rẹ̀, nwọn ni, Johanu Baptisti rán wa sọdọ rẹ, wipe, Iwọ li ẹniti mbọ̀, tabi ki a ma reti ẹlomiran?

Luk 7

Luk 7:13-23