Yorùbá Bibeli

Luk 7:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi o si ti sunmọ ẹnu bode ilu na, si kiyesi i, nwọn ngbé okú kan jade, ọmọ kanṣoṣo na ti iya rẹ̀, o si jẹ opó: ọ̀pọ ijọ enia ilu na si wà pẹlu rẹ̀.

Luk 7

Luk 7:4-20