Yorùbá Bibeli

Luk 5:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si pa owe kan fun wọn pẹlu pe, Kò si ẹniti ifi idãsa aṣọ titun lẹ ogbologbo ẹ̀wu; bikoṣepe titun fà a ya, ati pẹlu idãsà titun kò si ba ogbologbo aṣọ rẹ.

Luk 5

Luk 5:33-38