Yorùbá Bibeli

Luk 5:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wọ̀ ọkan ninu awọn ọkọ̀ na, ti iṣe ti Simoni, o si bẹ̀ ẹ ki o tẹ̀ si ẹhin diẹ kuro ni ilẹ. O si joko, o si nkọ́ ijọ enia lati inu ọkọ̀ na.

Luk 5

Luk 5:1-12