Yorùbá Bibeli

Luk 5:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ki ẹnyin ki o le mọ̀ pe, Ọmọ-enia li agbara li aiye lati dari ẹ̀ṣẹ jìni, (o wi fun ẹlẹgba na pe,) Mo wi fun ọ, Dide, si gbé akete rẹ, ki o si lọ si ile rẹ.

Luk 5

Luk 5:21-27