Yorùbá Bibeli

Luk 3:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹmí Mimọ́ si sọkalẹ si ori rẹ̀ li àwọ àdaba, ohùn kan si ti ọrun wá, ti o wipe, Iwọ ni ayanfẹ ọmọ mi; ẹniti inu mi dùn si gidigidi.

Luk 3

Luk 3:19-25