Yorùbá Bibeli

Luk 3:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

O dahùn o si wi fun wọn pe, Ẹniti o ba li ẹ̀wu meji, ki o fi ọkan fun ẹniti kò ni; ẹniti o ba si li onjẹ, ki o ṣe bẹ̃ pẹlu.

Luk 3

Luk 3:1-20