Yorùbá Bibeli

Luk 22:61 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si yipada, o wò Peteru. Peteru si ranti ọ̀rọ Oluwa, bi o ti wi fun u pe, Ki akukọ ki o to kọ, iwọ o sẹ́ mi li ẹrinmẹta.

Luk 22

Luk 22:53-66