Yorùbá Bibeli

Luk 20:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li o bẹ̀rẹ si ipa owe yi fun awọn enia pe; ọkunrin kan gbìn ọgba ajara kan, o si fi ṣe agbatọju fun awọn àgbẹ, o si lọ si àjo fun igba pipẹ.

Luk 20

Luk 20:7-12